Check Out Asake — Great Guy Lyrics

Artist: Asake 

Title Of Song: Great Guy

Year Of Release: 2023

Album Title: Work Of Art

Number Of Tracks: 14

Ọlọladé mí, Àṣakẹ

Tune into the king of sound and blues

 

I be the vibe you can see in my lifestyle

Ọmọ, mo soft, give them peace sign

Different pattern on my own style

So consistent, no resistance

Leader of the pack, you can call me a brave guy

Steady conquering, I be great guy

Man wey sleep, who go wake am?

This life be like rollercoaster

 

Ọmọ Ọlọhun, k’ómá s’ere o

Ko wa’lẹ, ibẹ ló ńgbé o

Tí ńba m’ọtí, mo má dé’lé o

J’ayé orí ẹ, wàṣeré o

Ọmọ Ọlọhun, k’ómá s’ere o

Ko wa’lẹ, ibẹ ló ńgbé o

Tí ńba m’ọtí, mo má dé’lé o

J’ayé orí ẹ, wàṣeré o

 

Satin wọ satin, Paris wọ Berlin

Kà ṣe mí

Orí mí, mà jẹ ńṣẹ̀sín

Ajé mo pé ní, kò jẹ mí

Àrà àdúgbò, ẹ gbà mí

Wọn ní mo tún tí ṣe mí, ṣé bí òun ẹ fẹ ní

I sabi, I no sabi

Party after party, I’m Gucci

Christian Dior, oh my Jesus

I will see you guys soon in the morning o

I gats to go dey with my baby o

Mm-mm, baby, lean on me

Jẹjẹly, jẹjẹly, jẹjẹ o (jẹjẹly)

Rọra gbẹ’nusì, ṣé jẹjẹ o (mm)

Ayé fẹlẹ o, k’ásẹ̀ pẹ’lẹ’ o

Ẹ gbé sókè, ẹ má jẹ o wa’lẹ

 

I be the vibe you can see in my lifestyle

Ọmọ, mo soft, give them peace sign

Different pattern on my own style

So consistent, no resistance

Leader of the pack, you can call me a brave guy

Steady conquering, I be great guy

Man wey sleep, who go wake am?

This life be like rollercoaster

 

Ọmọ Ọlọhun, k’ómá s’ere o

Ko wa’lẹ, ibẹ ló ńgbé o

Tí ńba m’ọtí, mo má dé’lé o

J’ayé orí ẹ, wàṣeré o

Ọmọ Ọlọhun, k’ómá s’ere o

Ko wa’lẹ, ibẹ ló ńgbé o

Tí ńba m’ọtí, mo má dé’lé o

J’ayé orí ẹ, wàṣeré o

 

Wáṣeré, o kéré

Ìjà lóde, l’orin d’òwe

Ọmọ ọba, mí o gbé’lé

Saati, mo gbélè, ajà mí lo ń sáaré

Never lose guard, mi o seke

So many things wey my eye don see

Irony, see reality

Normally, I get packaging

Ṣé you go like know, ask Tunde Ednut

CBD, ṣé you see me ri

MTV l’órí AIT

Jesus Christ, wọn fẹ Judas mí

Maybe before you four, five, six

You gats to one, two, three

Two plus two no be one (one, one)

I get the talent, no be cap

My time is prime

Bẹ sí wá kò kpayin, Luku wọ design

Ọmọ ìyámi, jẹ ko shine

 

Bien malevé

Bien malevé pou toi mo zene fam

Bien malevé pou toi mo zene fam

Tou saki ena so mari lor bateau

Mo trouve signaux signale

Mo trouve signaux signale

Mo trouve signaux signale, pas bateau talaba ki rentre

Leave a Reply

Manage push notifications

Contact Us